LG 15FC2RB Manuel Du Propriétaire page 33

Masquer les pouces Voir aussi pour 15FC2RB:
Table des Matières

Publicité

Les langues disponibles

Les langues disponibles

Teletext (tabi TOP text) je isẹ ti o se dan dan, fun
idi eyi, ẹrọ to ba ni anfani re lo le lo.
Teletext jẹ isẹ ọfẹ ti ọpọ ile TV ma n pese fun ekun
rẹrẹ iroyin, oju ọjọ, eto, ipin oye ati bẹẹbẹẹ lọ.
Decorder teletext TV yii lee se iranwo fun SIMPLE,
TOP ati FASTEXT. SIMPLE (standard teletext) eyi
ni nọmiba awọn oju ewe ti o tiwa ni idawole nipa fifi
nọmiba oju ewe si. TOP ati FASTEXT wa fun lati
gba iroyin ni kia kia ti igba lode.
Titan / pipa
Tẹ bọtini TEXT lati pada si teletext.
Oju ewee tele tabi to gbẹyin yio juyọ loju iran.
Awọn nọmiba oju ewe meji, oruko ilese TV igba
ati akoko yio jẹyọ loju iran. Nọmiba oju ewe akọkọ
tumọ si idawọle rẹ, ikeji si fi oju ewe tun tun han.
Tẹ bọtini TV/AV lati yi teletext pada. Ipo iṣaaju tun
han.
SIMPLE text
Inawole oju ewe
1. Fi nọmiba oju ewe mẹta ti o wu ọ julọ si pẹlu
bọtini NỌMIBA. Ti asise ba jẹyọ, ri daju wipe o
fi nọmiba meta to damuse si lẹẹkan si.
2. Bọtini
/
seé lo dawole oju ewe tateyin wa
D
E
ati eyi tokan.
Teletext (iyan)
Sisẹ eto bọtini onikolo ni LIST (iyan)
4
Tẹ bọtini
Nọmiba oju ewe teletext merin to wu ọ julọ seé lo
lati dari awọ orisirisi lori rimotu.
1. Tẹ bọtini alawọ kan.
2. Lo bọtini NỌMIBA, nawọ gan oju ewe ti o fẹ
seto le lori.
3. Tẹ bọtini OK. Lẹyin eyi oju ewe ti o ti nawọ gan
yio wa ninu apamọ nipa isẹju ina. Lati igba yi
lọ, o le yan abala yi pelu bọtini oni kọlọ.
4. Awọn bọtini alawọ mẹta to kun yio wa leto
bakan naa.
lati pada si isẹ LIST.
9

Publicité

Chapitres

Table des Matières
loading

Table des Matières