Ẹrọ amówùn-máwòrán aláwọ orísi-rísi
ÌWÉ ÌTỌSỌNÀ
Kío to lo ẹrọ yíì, jọwọ ka iwe ìtọnisọna yii dara-dara.
Tojú ree fún lilo ọjọ iwaju.
Ko nọmiba igba ati akoko ti wọn se ẹrọ yii sílẹ.
Ye iwe atọka ti a lẹ mọ ẹyin iwe itọsọna yii iwo, ki o si ri daju pe
o fi eyi sẹ ẹri to daju nigba ti o ba n wa iranlọwọ lati ọdọ awọn to
pese ẹrọ yii.
Nọmiba igba ti wọn see
Nọmiba bi wọn se tẹle ra wọn
:
:
www.lg.com