Ìfisìpò .................................................................. 2
Liloo pẹlu awọn ẹrọ miran .................................. 2
Aye ati isẹ isakoso ............................................. 3
Koko isẹ sisẹ ...................................................... 4
Owun elo oju iran ............................................... 4
Tito ẹrọ TV sitesọn ............................................. 5
Didari aworan ..................................................... 6
Titan ati pipa ẹrọ
Agbara inaa mọna-mọna ti ẹrọ yii n ba sisẹ ti wa lape-
juwe lekun rere leyin iwe yii. Mase fi waya inaa ẹrọ yii
si inaa mọna-mọna kia kia. Ti o ba sisẹ wipe ara san
tabi ina ja lori epo, yọ waya ẹrọ yii kuro nina.
Tẹ bọtini POWER lori panẹli iwaju tabi panẹli ẹgbẹ
lati paa TV nigbati ẹrọ TV ko si ni lilo fun igba pipẹ.
A ṣe iṣeduro pe ki o yọ pulọọgi kuro lati ara ogiri oju-
iṣan (Aaye agbara).
ẸRỌ GIGE ASOPỌ LATI AWỌN ASOMỌ
Pulọọgi awọn asomọ jẹ ẹrọ gige asopọ. Pulọọgi
gbọdọ wa ni imurasilẹ mu ṣiṣẹ.
Ìkìlọ
Lati daabo bo ara re lọwọ ina jijo ati giri inaa mọna-
mọna, mase je ki ojo tabi omi kan si ẹrọ yii.
Mase gbe onu kowu to san bi omi si ori ro yii rara,
eyi le fa ina jijo tabi giri inaa mọna-mọna.
Isẹ sisẹ lori ẹrọ
Mase yọ ike ehin ni kuro, ni tori ina ala agbara ti
Liloo pẹlu awọn ẹrọ miran
O le lo awọn ero bii VCRs, camcorders ati bẹẹbẹẹ
lọ pẹlu ẹrọ yii.
Oun ti oo ri mi yin yio yatọ si aworan ti ẹrọ rẹ yio
fun ọ.
Sọkẹti eriya
1. Fi sọkẹti RF ti VCR sin u sọkẹti eriya leyin ẹrọ yii.
2. Fi okun eriya si eriya RF ninu sọkẹti VCR.
3. Ki o fi sạnẹli VCR si nọmiba eto ti o wu ọ julọ
nipa lilo 'Siseto pẹlu ọwọre'.
4. Nawọ gan nọmiba eto ti o fi VCR si.
5. Tẹ bọtini PLAY lori VCR.
Sọkẹti Audio/Video ita/inủ (iyan)
1. Fi iho audio/video ti o wa ni ta lara VCR si iho
audio/video ti ẹrọ yii si iho sọkẹti VCR si inu
sọkẹti RF OUT.
2. Ti o ba fi VCR si iho AV, tẹ bọtini TV/AV lati ni
anfani si
tabi
.
A V1
A V2
3. Tẹ bọtini PLAY lorii VCR. Aworan idapada
sẹyin eto VCR yio lan lori ẹrọ.
O si tun le fi eto ori TV yii si mi apamọ video
tape nipa lilo iho sọkẹti audio/video.
Akiyesi : Ti o ba ni mono VCR, fi okun audio ti o
wa lati VCR si sọkẹti ẹrọ AUDIO L/MONO.
Sọkẹti Euro scart (iyan)
1. Fi sọkẹti Euro scart ti VCR si sọkẹti Euro scart
ti ẹrọ yii.
2
Ìtókùn
Didari ohun ......................................................... 7
Tito ago ọjọ......................................................... 8
Awọn isẹ miran ................................................... 8
Teletext (iyan) ..................................................... 9
Troubleshooting ayewo
Ìfisìpò
ole pa eniyan lara ati ninu awọn ewu. Ti ẹrọ yii o
ba sisẹ bo ti yẹ, yo waya rẹ kuro nina, ki o si ke pe
awọn to ń taa.
Eriya
Ri daju pe o fi okin eriya yii si aye rẹ ni bi ideri eyin
ẹrọ yii. Lati ni aworan to damuse lorii ẹrọ yii, eriya
olopo nit a ni ki o yan.
Aye
Ri daju pẹ aye ti o gbe ẹrọ yii si kọ dioju kọ oorin
tabi ina to mọlẹ. Ri daju pe o daabo bo ẹrọ yii lorii
gbigbọn, oru ati eruhu. Ki o si ri daju pe ẹrọ yii wa
nibi ti afẹfẹ wa dara dara. Mase fi onu kowu bo aye
to wa fun afẹfẹ lati wọle ni ideri eyin ẹrọ yii.
Akiyesi:
(iyan)
Ti o ba fẹ gbọn idọti mi kuro loju ẹrọ TV re jowo lo
aso ti a pese pẹlu ẹrọ yii. Mase fi gbogbo okun rẹ
mi idọti yii ki o ma ba bakọnjẹ lara ẹrọ yii.
2. Tẹ bọtini PLAY lori VCR.
Fi sọkẹti Euro scart ti VCR si sọkẹti Euro scart
ẹrọ yio si yi pada si
ba fe wo eto inu ẹrọ TV yii, te
NỌMIBA.
Lai si eyi te bọtini TV/AV lori ẹrọ rimotu lati
nawọ gan
A V1
han loju iran.
O si tan le fie to inu TV si mi apamọ video tape.
Akiyesi : Ifi han RGB, eyi to tumọ pupa, alawo
ewe ati bulu nikan mi o le nawọ gan lorii sọkẹti
O le ri awọn ifihan yii ni pa sẹ TV
Euro scart.
decorder ti o san wo fun, ẹrọ game tabi photo CD
unit, ati bẹẹbẹẹ lọ.
Awọn komponeti ohun ti o mbe ninu
sọkẹti (iyan)
1. Fi COMPONENT sọkẹti video output (Y Cb Cr,
Y Pb Pr tabi Y B-Y R-Y) ti COMPONENT (480i)
si sọkẹti COMPONENT INPUT (Y P
ẹrọ yii.
2. Fi okun ina audio lati idi COMPONENT si
sọkẹti AUDIO IN ti AV IN2.
3. Tẹ bọtini TV/AV lati nawọ gan
4. Tẹ bọtini PLAY lorii COMPONENT. Aworan
idapada seyin COMPONENT yio yọ loju iran.
fun ara rẹ. Sugbọn ti o
A V1
/
tabi bọtini
D
E
. Aworan ipadasẹyin VCR yio
P
) lori
B
R
COMPONENT
.